AÁYAN ÒGBUFỌ̀
Kín ni itumọ Aayan ogbufo? Aáyan ògbufọ̀ ni itumọ ede lati ede kan si omiran, paapaa julo ede geesi si
ede Yoruba.
ÀMÚYẸ FÚN ÒGBUFỌ̀
1. Gbigbo ede mejeeji: a gbodo gbo ede mejeeji daradara, eyi ni ede ti yoo tumo ati ede ti yoo tumo re
si.
2. Mimo ko ati mimo kaa: ogbufo gbodo le ka ede mejeeji daradara nitori pe akosile ede geesi ni won
yoo gbe fun wa lati tumo.
Apẹẹrẹ Ogbufo Gbolohun Die
Ede Geesi Itumo Lede Yoruba
1. He was ashamed of his behaviour Oju tii nitori iwa a re
2. The headmaster permited the. Oga ile eko na fun awon
children to go home akekoo laye lati lo sile
3. The tortoise tricked the Ijapa tan ekun naa je o si ti mo
tiger and caged it at last. inu aago leyin- o-reyin
4. It rained cats and dogs in Lagos yesterday Ojo ro ofeere wu oku ole ni ilu Eko lana
5. Whoever beaks any of these golden rules Enikeni ti o ba ru eyikeyi ninu awon ofin
will have himself to blame. pataki wonyi yio dara re lebi
Aayan ogbufo ti wa lati odun pipe alufaa Samuel Ajayi Crowther ni eni ti o tumo iwe mimo bibeli
ede oyinbo si ede yoruba ni odun 1844-1856
ILANA TITUMO EDE
a. A gbodo ni imo pipe lori ede ti a fe tumo
b. Ba kan naa, a gbodo ni imo pipe lori ede ti a fe tumo re si
ORÍSÌÍ Ọ̀NÀ TÍ A LE GBÀ TÚMỌ̀ AÁYAN ÒGBUFỌ̀
a. Ojulowo itumo : Eyi ni ti tumo oro ni ikookan bi won se wa ninu ede ti a fe tumo si ede keji
b. Itumo afarajora : Eyi ni ki a mu gbolohun oro inu ede ti a fe tumo ki a lo oro ti o bamu regi ninu ede ti
a n tumo re si Ni kukuru, itumo afarajora ni fifi oye ede ti wa gbe itumo kale
EDE GEE SI EDE YORUBA
Audience. Onworan
Competition Idije
Joke Àpárá
Overlap Wonu ara
Research Iwadii
Transfer Isinipo
Motivate Moriya
Pattern. Batani
Stage Ori itage
Idea Oye
AAYAN OGBUFO NI ILE O'DUA.
Ayan ogbufo je ede omo oduduwa ti a le tumo si ede Geesi. Awon bi.
1. Aiku ekiri laiye, ko si eniti o ma fi awo re se gbedu.
When the bush goat is still alive, his skin cannot be used for a drum.
2. Ajo ki dun, ki onile ma re le.
A foreign land is never so attractive that one would not prefer to go home.
3. Akuko ko, ole pose.
When the cock crows, the lazy/slothful smacks his lips.
4. Alaso ala, ki n wo iso elepo.
He who wears a white suit should avoid the palm oil stall
5. Bi aja ba ri oju ekun apa lolo
A dog keeps quiet on seeing a lion.
6. Eni ba mo aiye je, ki n gun agbon.
One who knows how to enjoy life should not climb coconut trees.
7. Adaba nfogede, ose bi eiyele ko gbo, eiyele gbo tiri-tiri lo n tiri.
The dove pronounces some charms and thinks the pigeon does not comprehend. The pigeon does
understand but does not trouble to take any notice.
8. Aguntan ti o ba ba aja rin, aje igbe.
The sheep that associates with dog shall eat dung
9. Orisa ti yio se bi Ogun kosi, oju lasan ni gbogbo won nya.
There is no god who can act like the god of iron, the rest are only boasting
10. Eni ba sun ni aanji, a ki n ji apiroro.
It's a sleeper who should be waked, not a pretender.